Skip to content
Hadith TranslationsHadith translations · ترجمة الأحاديث
Hadith · 6021 · YorùbáSource ↗

”Eyi ti o lẹtọọ julọ ninu awọn majẹmu lati mu ṣẹ ni nnkan ti ẹ fi sọ awọn abẹ di ẹtọ” - Hadith Translation

Lati ọdọ ‘Uqbah ọmọ ‘Aamir- ki Ọlọhun yọnu si i- o sọ pe: Ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pé: ”Eyi ti o lẹtọọ julọ ninu awọn majẹmu lati mu ṣẹ ni nnkan ti ẹ fi sọ awọn abẹ di ẹtọ”.
Narrated by
Ohun ti wọ́n fi ẹnu kò lé lórí ni
Grade
O ni alaafia

أحق الشروط أن توفوا به ما استحللتم به الفروج

عن عقبة بن عامر رضي الله عنه قال: قال رسول الله صلى الله عليه وسلم: «أَحَقُّ الشُّرُوطِ أَنْ تُوفُوا بِهِ مَا اسْتَحْلَلْتُمْ بِهِ الْفُرُوجَ».

متفق عليه · صحيح

النص العربي والتخريج وجميع الترجمات

Other languages